sentence
stringlengths
14
109
root
stringlengths
2
6
root_meaning
stringlengths
3
64
ẸTÙ méjì ni a ní nílé tí a ń sìn
ẸTÙ
GUINEA FOWL
Ìwọ́ we mọ ọmọ náà lọrùn nigbati ìyá rẹ̀ bí I
Ìwọ́
Umbilical cord
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ sí ilé olùkọ́ lati pọn omi sùgbọ́n wọn ò mú igbá lọ́wọ́
Igbá
fetcher
Ri dájú pé o ra ògùn fún ikun tí o mu ọ
Ikun
Mucus
Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi
KẸ́KẸ́
A PECULIAR FACIAL MARK
Olukọ ní kí ọmọ ile-iwe kọọkan mu ọwọ̀ kọọkan wa
Ọwọ̀
Broom
Awọn ọmọ ogun oril'ede yìí ṣetán láti bá àwọn agbesunmomi jagun
Jagun
To make war
Taani òye ayé yìí yé, kí ó wá sọ
AYÉ
EARTH
ìyá ra bàtà tuntun fún ọmọ rẹ̀
Bàtà
Shoe
Ọwọ́ àwọn agbofinró tẹ ọkùnrin tó n ta igbó
Igbó
India helm
Pátákò Ẹfọ̀n, kakaka lo má ń ta ajá lẹ́nu
PÁTÁKÒ
HOOF
Àwọn Ikán yìí nílò àmójútó gidigidi
IKÁN
TERMITE
Ọbẹ̀ ilá pẹlú gbegiri a máa dùn lórí amala
Ilá
Okro
Ní bo ìyá ìkókó gbà lọ
ÌKÓKÓ
BABY
Ìná àpà ni Kúnlè ná fún olorin
Ìná
spent
Ìlú Adà ni ìyá Rọlakẹ ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀
ADÀ
A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA
Bàbá mí ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní àná
Ọkọ̀
CAR
Ó ní láti gbọ́n epo ra ojú Ówo náà kí ó lè tètè dẹ̀
ÓWO
BOIL
Ọ̀gà inú ayanran mi ti sá lọ
Ọ̀GÀ
CHAMELEON
Ọ̀dẹ̀ ni gbogbo wa yóò jókòó sí lónìí
Ọ̀DẸ̀
PASSAGE
Solape ń gbìyànjú láti gba ilé-ìtajà sí bẹrẹ
BẸRẸ
AN AREA IN IBADAN, OYO STATE
Ma se sọ ọ̀rọ̀ òdì sí ọmọ ẹní Kejì rẹ
Òdì
other side of something
Ọmọ náà jẹun sí ikùn tí o sì yó
Ikùn
Stomach
Bàbá Atinukẹ ní oko ńlá mẹ́ta tí ó fi gbin ikàn
IKÀN
GARDEN EGG
Ìgbò ni Ṣọla fi má n bori awọn alátakọ̀ rẹ̀ nígbà tí ìjà bá wáyé-
Ìgbò
headbutt
Ti igbó ba pọ̀ ní àyíká, o le ṣe òkùnfà ẹ̀fọn
Igbó
Bush
Awò ni àwọn dókítà fún Olabisi tí sọnù
AWÒ
SPECTACLE
Iyè ọmọ náà ti ra pẹ̀lú ibẹru
IYÈ
MIND
lọ ká ìtẹ́ tí o fi sún
Ìtẹ́
Mat
Bí a múra sí iṣẹ ọwọ ẹni oseese kìí ìṣẹ́ jìnà sí ni
Ìṣẹ́
poverty
Iwe adìẹ náà kún mi lẹ́nu púpọ̀
IWE
GIZZARD
Ọgbọ̀n ọjọ́ ni o wà nínú osù kẹrin
Ọgbọ̀n
Thirty
Àsá tí ó gbémi ni adìẹ, kò ní pẹ́ bá ọlọ́jọ́ pàdé
ÀSÁ
EAGLE
Ìlà ti adari ayo fa silẹ ni agbaboolu naa fi'binu parẹ́ ti o fi gba kaadi pupa
Ìlà
line
Ìkòkò ìyá àgbà tí fọ́ yángá-yángá
ÌKÒKÒ
LOCAL POT
Ọmọ bíbí ìlú Ọ̀wọ̀ ni Gomina ipinlẹ Òndó àná
Ọ̀wọ̀
A town in Ondo State
Olùkọ́ àgbà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní owó láti fi ra oúnjẹ
Owó
money
jagunjagun náà fí ọ̀kọ̀ gba ara rẹ̀ lẹ ní ojú Ogun
Ọ̀kọ̀
spare
Ìlú Awó kò jìnnà sí ìlú Gómìnà
AWÓ
A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
Ègbo díẹ̀ àti ẹ̀wà díẹ̀ ti tó fún un èmi
ÈGBO
FOOD DERIVED FROM MAIZE
Ogun jalumi kìí se tí ènìyàn lè gbàgbé
OGUN
WAR
Lẹ́yìn tí a fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ iyán tán, bàbá àgbá pa aalọ fún un wa
TẸ̀TẸ̀
A VARIETY OF VEGETABLE
Pátákó ajúwe lo jẹ́ atọ́na láti dé ilé ìjọsìn naa
PÁTÁKÓ
PLANT, BOARD
Owó àjọ máa ń bo ènìyàn ní àṣírí púpọ̀
ÀJỌ
CONTRIBUTION
Fọlákẹ́ fi ogún ẹgbẹ̀rún s'owo, o sí jẹ èrè ẹgbẹrun máàrún
Èrè
Gain/Profit
Ìsín ni ó pọ̀ jù ni odò adágún inú oko mi
ÌSÍN
SMALL CATFISH
Eré ni Ṣọla ati Dayọ nṣe ki o tó d'ija
Eré
Play/Drama
Ishola rí owó ribiribi níbi ọkà oko rẹ̀ ni ọdún yìí
ỌKÀ
GUINEA CORN
Ohun amohunmaworan rẹ ni lọ sókè ju
Ohùn
Sound
Àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ yóò yọjú sì Kábíyèsí ní òṣùpá mẹta tó ń bọ̀
Ẹ̀SÌN
RELIGION
Ọmọ náà ni ọ̀wọ́ lẹyìn
Ọ̀wọ́
Group/ Collectively
eegún tí yóò erin kò sí nígbó
Eegún
masqurade
Bí ajá bá rí olówó Re yíò ju ìrù sí
Ìrù
tail
Awọn olè se ọkùnrin naa ni osẹ́ púpọ̀
Ọsẹ́
injury
Irọ̀ ni èmi àti Adeyọde
IRỌ̀
AGE MATE
Àgbà kì í wà lọ́jà, kí orí ọmọ tuntun kó wọ́
ÀGBÀ
ELDERLY PERSON
wakati meji ni ọkọ ayọkẹlẹ yóò lo lọnà láti ìlú ìlá sí ìlú Osogbo
Ìlá
a town in Osun state
Ará kannáà ni ìran ìbíní àti yorùbá jẹ́
Ará
related people
Orí òró ni àwọn òní janduku pa ọkùnrin náà sí
ÒRÓ
STAND
ìyàwó tí ọkọ fẹràn jù lo ń se ọbẹ̀ fún ọkọ
Ọkọ
husband
Ìlú Ìbàdàn ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ ní òpin ọ̀sẹ̀
Ìlú
Village
Bí obìnrin bá fi ojú di orò, yóò dá ara rẹ̀ ni ẹ̀bi
ORÒ
A god in Yoruba land